Check out the new design

Fassarar Ma'anonin Alqura'ni - Fassarar Yarabanci - Abu Ruhaimah Mika'il * - Teburin Bayani kan wasu Fassarori

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Fassarar Ma'anoni Aya: (3) Sura: Al'bakara
ٱلَّذِينَ يُؤۡمِنُونَ بِٱلۡغَيۡبِ وَيُقِيمُونَ ٱلصَّلَوٰةَ وَمِمَّا رَزَقۡنَٰهُمۡ يُنفِقُونَ
(Àwọn olùbẹ̀rù Allāhu ni:) àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo nínú ìkọ̀kọ̀[1] àti àwọn tó ń kírun àti àwọn tó ń ná nínú ohun tí A pèsè fún wọn,
[1] Ìkọ̀kọ̀ ni ohun tí ẹ̀dá kò lè fi ọ̀nà kan kan nímọ̀ nípa rẹ̀ nínú ohun tí Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀ - sọllallāhu alaehi wa sallam - sọ nípa rẹ̀.
Tafsiran larabci:
 
Fassarar Ma'anoni Aya: (3) Sura: Al'bakara
Teburin Jerin Sunayen Surori Lambar shafi
 
Fassarar Ma'anonin Alqura'ni - Fassarar Yarabanci - Abu Ruhaimah Mika'il - Teburin Bayani kan wasu Fassarori

Fassara Sheikh Abu Ruhaimah Mika'il Aikuyini.

Rufewa