ترجمة معاني القرآن الكريم - الترجمة اليورباوية * - فهرس التراجم

PDF XML CSV Excel API
تنزيل الملفات يتضمن الموافقة على هذه الشروط والسياسات

ترجمة معاني آية: (21) سورة: البقرة
يَٰٓأَيُّهَا ٱلنَّاسُ ٱعۡبُدُواْ رَبَّكُمُ ٱلَّذِي خَلَقَكُمۡ وَٱلَّذِينَ مِن قَبۡلِكُمۡ لَعَلَّكُمۡ تَتَّقُونَ
Ẹ̀yin ènìyàn, ẹ jọ́sìn fún Olúwa yín, Ẹni tí Ó dá ẹ̀yin àti àwọn tó ṣíwájú yín, nítorí kí ẹ lè ṣọ́ra (fún ìyà Iná).¹
1. Kalmọh “لَعَلَّ” “la‘alla” ní ìtúmọ̀ mẹ́ta. Ìrètí, nítorí àti ìgbájúmọ́. (Ƙurtubiy) Ìyẹn túmọ̀ sí pé, ﴿ لَعَلَّكُمْ تَتَّقُونَ ﴾ máa túmọ̀ sí (1) Bí ẹ bá ń jọ́sìn fún Allāhu, ìrètí wà fún yín pé ẹ máa di olùbẹ̀rù Rẹ̀. (2) Nítorí kí ẹ lè ṣọ́ra fún Iná, ẹ máa jọ́sìn fún Allāhu. Ìyẹn ni pé, kò sí ọ̀nà mìíràn láti fi ṣọ́ra fún Iná bí kò ṣe jíjọ́sìn fún Allāhu. (3) Ẹ gbájúmọ́ ìbẹ̀rù Allāhu nípasẹ̀ àṣẹ t'Ó pa yín pé kí ẹ máa jọ́sìn fún Un.
التفاسير العربية:
 
ترجمة معاني آية: (21) سورة: البقرة
فهرس السور رقم الصفحة
 
ترجمة معاني القرآن الكريم - الترجمة اليورباوية - فهرس التراجم

ترجمة معاني القرآن الكريم إلى اللغة اليوربا، ترجمها الشيخ أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني. طبعة عام 1432هـ .

إغلاق