ترجمة معاني القرآن الكريم - الترجمة اليورباوية * - فهرس التراجم

PDF XML CSV Excel API
تنزيل الملفات يتضمن الموافقة على هذه الشروط والسياسات

ترجمة معاني آية: (3) سورة: فصلت
كِتَٰبٞ فُصِّلَتۡ ءَايَٰتُهُۥ قُرۡءَانًا عَرَبِيّٗا لِّقَوۡمٖ يَعۡلَمُونَ
Tírà kan ni tí wọ́n ṣàlàyé àwọn āyah inú rẹ̀,¹ (ó ń jẹ́) al-Ƙur’ān (tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ ní) èdè Lárúbáwá fún ìjọ tó nímọ̀.
1. Ìtúmọ̀ mìíràn “Tírà kan ni tí wọ́n pín àwọn āyah inú rẹ̀ sínú àwọn sūrah.” (Tafsīr at-Tashīl li ‘ulūmi-ttanzīl libn Juziy).
Wàyí nípa ti ìtúmọ̀ àkọ́kọ́ “Tírà kan ni tí wọ́n ṣàlàyé àwọn āyah inú rẹ̀”, kí ni n̄ǹkan náà tí wọ́n fi ṣàlàyé àwọn āyah inú al-Ƙur’ān? Ní àyè yìí ni a óò ti mọ pàtàkì àwọn hadīth Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá -. Ìdí ni pé, gbogbo àwọn āyah tí ó jẹmọ́ ìgbàgbọ́ òdodo “al-‘aƙīdah” àti àwon āyah tó jẹmọ́ ìjọ́sìn “al-‘ibādah” àti àwọn āyah tó jẹmọ́ òfin àti ìdájọ́ “al-hukm wal-ƙọdọ̄’, kò sí àlàyé wọn nínú al-Ƙur’ān bí kò ṣe nínú àwọn hadīth Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá -.
التفاسير العربية:
 
ترجمة معاني آية: (3) سورة: فصلت
فهرس السور رقم الصفحة
 
ترجمة معاني القرآن الكريم - الترجمة اليورباوية - فهرس التراجم

ترجمة معاني القرآن الكريم إلى اللغة اليوربا، ترجمها الشيخ أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني. طبعة عام 1432هـ .

إغلاق