Translation of the Meanings of the Noble Qur'an - Yoruba translation * - Translations’ Index

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Translation of the meanings Ayah: (149) Surah: Al-An‘ām
قُلۡ فَلِلَّهِ ٱلۡحُجَّةُ ٱلۡبَٰلِغَةُۖ فَلَوۡ شَآءَ لَهَدَىٰكُمۡ أَجۡمَعِينَ
Sọ pé: “Ti Allāhu ni ẹ̀rí tó dópin.¹” Nítorí náà, tí Ó bá fẹ́ ni, ìbá fi gbogbo yín mọ̀nà pátápátá.”
1. Ẹ̀rí tó dópin ni ẹ̀rí apayànjẹ (ẹ̀rí tó ń pa iyàn jíjà jẹ), ẹ̀rí tó dé ògòńgó.
Arabic explanations of the Qur’an:
 
Translation of the meanings Ayah: (149) Surah: Al-An‘ām
Surahs’ Index Page Number
 
Translation of the Meanings of the Noble Qur'an - Yoruba translation - Translations’ Index

Translation of the Quran meanings into Yoruba by Abu Rahima Mikhail Aikweiny, printed in 1432 H.

close