ترجمهٔ معانی قرآن کریم - ترجمه ى یوروبایی * - لیست ترجمه ها

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

ترجمهٔ معانی آیه: (10) سوره: سوره بقره
فِي قُلُوبِهِم مَّرَضٞ فَزَادَهُمُ ٱللَّهُ مَرَضٗاۖ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمُۢ بِمَا كَانُواْ يَكۡذِبُونَ
Àrùn kan wà nínú ọkàn wọn¹, nítorí náà Allāhu ṣe àlékún àrùn fún wọn.² Ìyà ẹlẹ́ta-eléro sì wà fún wọn nítorí pé wọ́n ń parọ́.
1. Àrùn iyèméjì àti ìṣojúméjì sí āyah al-Ƙur’ān.
2. Ìyẹn ni pé, àrùn ọkàn wọn ń lékún sí i nígbàkígbà tí āyah bá sọ̀kalẹ̀ tí wọ́n ń takò ó.
تفسیرهای عربی:
 
ترجمهٔ معانی آیه: (10) سوره: سوره بقره
فهرست سوره ها شماره صفحه
 
ترجمهٔ معانی قرآن کریم - ترجمه ى یوروبایی - لیست ترجمه ها

ترجمه ى معانی قرآن کریم به زبان یوروبایی. مترجم: شیخ ابو رحیمه میکائیل ایکوینی. سال چاپ: 1432هجرى قمرى.

بستن