Vertaling van de betekenissen Edele Qur'an - Yoruba vertaling * - Index van vertaling

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Vertaling van de betekenissen Vers: (90) Surah: Soerat El-Maidah (De tafel)
يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ إِنَّمَا ٱلۡخَمۡرُ وَٱلۡمَيۡسِرُ وَٱلۡأَنصَابُ وَٱلۡأَزۡلَٰمُ رِجۡسٞ مِّنۡ عَمَلِ ٱلشَّيۡطَٰنِ فَٱجۡتَنِبُوهُ لَعَلَّكُمۡ تُفۡلِحُونَ
Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, dájúdájú ọtí,¹ tẹ́tẹ́, àwọn òrìṣà àti iṣẹ́ yíyẹ̀wò², ẹ̀gbin nínú iṣẹ́ Èṣù ni. Nítorí náà, ẹ jìnnà sí i nítorí kí ẹ lè jèrè.
1. Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-Baƙọrah; 2:219.
2. Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ āyah 3.
Arabische uitleg van de Qur'an:
 
Vertaling van de betekenissen Vers: (90) Surah: Soerat El-Maidah (De tafel)
Surah's Index Pagina nummer
 
Vertaling van de betekenissen Edele Qur'an - Yoruba vertaling - Index van vertaling

betekenissen in Yoruba door Abu Rahima Mikhail Aikweiny, gedrukt in 1432 H.

Sluit