அல்குர்ஆன் மொழிபெயர்ப்பு - யொரூபா மொழிபெயர்ப்பு * - மொழிபெயர்ப்பு அட்டவணை

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

மொழிபெயர்ப்பு வசனம்: (35) அத்தியாயம்: ஸூரா அல்மாயிதா
يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ ٱتَّقُواْ ٱللَّهَ وَٱبۡتَغُوٓاْ إِلَيۡهِ ٱلۡوَسِيلَةَ وَجَٰهِدُواْ فِي سَبِيلِهِۦ لَعَلَّكُمۡ تُفۡلِحُونَ
Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, ẹ bẹ̀rù Allāhu, kí ẹ sì wá àtẹ̀gùn sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀.¹ Ẹ jagun sí ojú-ọ̀nà Rẹ̀ nítorí kí ẹ lè jèrè.
1. Àtẹ̀gùn ni iṣẹ́ rere tí mùsùlùmí yóò máa ṣe láti fi súnmọ́ Allāhu. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àtẹ̀gùn, nínú èdè, ó lè tún túmọ̀ sí kí ẹnì kan lo ẹlòmíìràn láti súnmọ́ ẹnì kan, kì í ṣe èyí ni ìtúmọ̀ rẹ̀ àti ohun tí wọ́n gbàlérò nínú āyah yìí nítorí pé, ẹ̀sìn kì í ṣe ohun àbáṣe, bí kò ṣe pé ó jẹ́ ọ̀ran-anyàn orí-ò-jorí. Àwọn ọ̀ṣẹbọ di ọ̀ṣẹbọ nípasẹ̀ pé wọ́n ń pe àwọn kan lẹ́ni tí ó gbà pé àwọn ni àtẹ̀gùn sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́hun. Nínú ẹ̀sìn, iṣẹ́ rere ni àtẹ̀gùn sí ọ̀dọ̀ Allāhu, kì í ṣe ènìyàn ni àtẹ̀gùn.
அரபு விரிவுரைகள்:
 
மொழிபெயர்ப்பு வசனம்: (35) அத்தியாயம்: ஸூரா அல்மாயிதா
அத்தியாயங்களின் அட்டவணை பக்க எண்
 
அல்குர்ஆன் மொழிபெயர்ப்பு - யொரூபா மொழிபெயர்ப்பு - மொழிபெயர்ப்பு அட்டவணை

அபு ரஹிமா, மைக்கேல் ஐகோயெனி மொழிபெயர்த்த யொரூபா மொழிபெயர்ப்பு, பதிப்பு 1432

மூடுக