Check out the new design

Prijevod značenja časnog Kur'ana - Prijevod na joruba jezik - Ebu Rahime Mikail * - Sadržaj prijevodā

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Prijevod značenja Ajet: (34) Sura: El-A'araf
وَلِكُلِّ أُمَّةٍ أَجَلٞۖ فَإِذَا جَآءَ أَجَلُهُمۡ لَا يَسۡتَأۡخِرُونَ سَاعَةٗ وَلَا يَسۡتَقۡدِمُونَ
Àkókò kan ti wà fún ìjọ kọ̀ọ̀kan; nígbà tí àkókò wọn bá sì dé, wọn kò níí lè sún sẹ́yìn fún wákàtí kan, wọn kò sì níí lè sún ṣíwájú (àkókò naa).[1]
[1] Ìyẹn ni pé, ìkánjú láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá kò lè sún un sẹ́yìn ní ọjọ́ tí ó bá ṣẹlẹ̀, ẹ̀bẹ̀ àti àdúà kan láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá kò sì lè sún un ṣíwájú.
Tefsiri na arapskom jeziku:
 
Prijevod značenja Ajet: (34) Sura: El-A'araf
Indeks sura Broj stranice
 
Prijevod značenja časnog Kur'ana - Prijevod na joruba jezik - Ebu Rahime Mikail - Sadržaj prijevodā

Preveo šejh Ebu Rahime Mikail Ajkoniji.

Zatvaranje