Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo - Firo yurbawiiwo * - Tippudi firooji ɗii

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Firo maanaaji Simoore: Simlore ñiiwo (al-fiil)   Aaya:

Suuratul-Fiil

أَلَمۡ تَرَ كَيۡفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصۡحَٰبِ ٱلۡفِيلِ
Ṣé o kò wòye sí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ìjọ elérin ni?
Faccirooji aarabeeji:
أَلَمۡ يَجۡعَلۡ كَيۡدَهُمۡ فِي تَضۡلِيلٖ
Ṣé kò sọ ète wọn di òfo àti anù bí?
Faccirooji aarabeeji:
وَأَرۡسَلَ عَلَيۡهِمۡ طَيۡرًا أَبَابِيلَ
Ó sì rán àwọn ẹyẹ níkọ̀níkọ̀ sí wọn.
Faccirooji aarabeeji:
تَرۡمِيهِم بِحِجَارَةٖ مِّن سِجِّيلٖ
Wọ́n ń jù wọ́n ní òkúta amọ̀ (tó ti gbaná sára).
Faccirooji aarabeeji:
فَجَعَلَهُمۡ كَعَصۡفٖ مَّأۡكُولِۭ
Ó sì sọ wọ́n di bíi pòpórò gbígbẹ tí ẹranko jẹ lájẹdàsílẹ̀.
Faccirooji aarabeeji:
 
Firo maanaaji Simoore: Simlore ñiiwo (al-fiil)
Tippudi cimooje Tonngoode hello ngoo
 
Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo - Firo yurbawiiwo - Tippudi firooji ɗii

Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo e ɗemngal yurba, firi ɗum ko mawɗo Abuu Rahiima Miikaa'iil aykuuniy. Muulngo hitaande 1432fergo

Uddude