Traduction des sens du Noble Coran - Traduction en yorouba * - Lexique des traductions

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Traduction des sens Verset: (77) Sourate: AL ‘IMRÂN
إِنَّ ٱلَّذِينَ يَشۡتَرُونَ بِعَهۡدِ ٱللَّهِ وَأَيۡمَٰنِهِمۡ ثَمَنٗا قَلِيلًا أُوْلَٰٓئِكَ لَا خَلَٰقَ لَهُمۡ فِي ٱلۡأٓخِرَةِ وَلَا يُكَلِّمُهُمُ ٱللَّهُ وَلَا يَنظُرُ إِلَيۡهِمۡ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ وَلَا يُزَكِّيهِمۡ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمٞ
Dájúdájú àwọn tó ń ta májẹ̀mu Allāhu àti ìbúra wọn ní owó kékeré, àwọn wọ̀nyẹn, kò níí sí ìpín oore kan fún wọn ní Ọjọ́ Ìkẹ́yìn. Allāhu kò níí bá wọn sọ̀rọ̀, kò sì níí ṣíjú wò wọ́n ní Ọjọ́ Àjíǹde.¹ Kò sì níí fọ̀ wọ́n mọ́ (nínú ẹ̀ṣẹ̀) Ìyà ẹlẹ́ta-eléro sì ń bẹ fún wọn.
1. Āyah yìí kò tako sūrah as-Sọ̄fāt; 37:24-25. Àmọ́ ìtúmọ́ “Allāhu kò níí bá wọn sọ̀rọ̀” ni pé, Allāhu kò níí bá wọn sọ̀rọ̀ ìdùnnú ní ọjọ́ Àjíǹde, bí kò ṣe ọ̀rọ̀ ìbànújẹ́. Ìtúmọ̀ “kò sì níí ṣíjú wò wọ́n ní Ọjọ́ Àjíǹde” ni pé, “Allāhu kò níí fi ojú àánú wò wọ́n bí kò ṣe ojú ìyà tí ó máa jẹ wọ́n.
Les exégèses en arabe:
 
Traduction des sens Verset: (77) Sourate: AL ‘IMRÂN
Lexique des sourates Numéro de la page
 
Traduction des sens du Noble Coran - Traduction en yorouba - Lexique des traductions

Traduction des sens du Noble Coran en langue yorouba par Cheikh Abû Rahimah Mikhaïl Aikweiny et publiée en l'an 1432 de l'Hégire.

Fermeture