クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 * - 対訳の目次

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

対訳 節: (47) 章: 蜜蜂章
أَوۡ يَأۡخُذَهُمۡ عَلَىٰ تَخَوُّفٖ فَإِنَّ رَبَّكُمۡ لَرَءُوفٞ رَّحِيمٌ
Tàbí (Allāhu) kò lè máa gbá wọn mú díẹ̀díẹ̀ ni?¹ Nítorí náà, dájúdájú Olúwa yin má ni Aláàánú, Oníkẹ̀ẹ́.
1. “‘Alā takawwuf” nínú āyah yìí tún túmọ̀ sí pé, “Tàbí (Allāhu) kò lè máa gbá wọn mú pẹ̀lú ẹ̀rù tí ó máa ti wà lára wọn nípa irú ìyà wo ni Allāhu máa fi jẹ wọ́n, tàbí irú àdánwò wo ni Ó máa dẹ sí wọn.”. Èyí ni ìtúmọ̀ tí Ibn Kathīr fún un. Àmọ́ ìtúmọ̀ tí Tọbariy fún un ni mo lò. Méjèèjì náà sì ni ìtúmọ̀ “‘Alā takawwuf”.
アラビア語 クルアーン注釈:
 
対訳 節: (47) 章: 蜜蜂章
章名の目次 ページ番号
 
クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 - 対訳の目次

クルアーン・ヨルバ語対訳 - Abu Rahima Mikhail Aikweiny ヒジュラ暦1432年印刷

閉じる