クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 * - 対訳の目次

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

対訳 節: (25) 章: 預言者たち章
وَمَآ أَرۡسَلۡنَا مِن قَبۡلِكَ مِن رَّسُولٍ إِلَّا نُوحِيٓ إِلَيۡهِ أَنَّهُۥ لَآ إِلَٰهَ إِلَّآ أَنَا۠ فَٱعۡبُدُونِ
A kò rán òjíṣẹ́ kan níṣẹ́ ṣíwájú rẹ àfi kí A fi ìmísí ránṣẹ́ sí i pé: “Dájúdájú kò sí ọlọ́hun kan tí ẹ gbọ́dọ̀ jọ́sìn fún ní ọ̀nà òdodo àyàfi Èmi (Allāhu). Nítorí náà, ẹ jọ́sìn fún Mi.”¹
1. Āyah yìí ti fi hàn kedere pé, irú àwọn Ọ̀rúnmìlà kì í ṣe Òjíṣẹ́ Allāhu nítorí pé, irú wọn kò pe ayé lọ síbi “Dájúdájú kò sí ọlọ́hun kan tí a gbọ́dọ̀ jọ́sìn fún ní ọ̀nà òdodo àyàfi Allāhu.” Dípò èyí, ẹbọ ṣíṣe ni irú àwọn Ọ̀rúnmìlà gbé’lé ayé ṣe. Ẹbọ ṣíṣe sì ni ìpèpè irú wọn.
アラビア語 クルアーン注釈:
 
対訳 節: (25) 章: 預言者たち章
章名の目次 ページ番号
 
クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 - 対訳の目次

クルアーン・ヨルバ語対訳 - Abu Rahima Mikhail Aikweiny ヒジュラ暦1432年印刷

閉じる