Check out the new design

クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 - Abu Rahima Mikhail * - 対訳の目次

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

対訳 節: (106) 章: 悔悟章
وَءَاخَرُونَ مُرۡجَوۡنَ لِأَمۡرِ ٱللَّهِ إِمَّا يُعَذِّبُهُمۡ وَإِمَّا يَتُوبُ عَلَيۡهِمۡۗ وَٱللَّهُ عَلِيمٌ حَكِيمٞ
Wọ́n so ọ̀rọ̀ àwọn yòókù rọ̀ ná títí àṣẹ Allāhu máa fi dé; yálà kí Ó jẹ wọ́n níyà tàbí kí Ó gba ìronúpìwàdà wọn.[1] Allāhu sì ni Onímọ̀, Ọlọ́gbọ́n. [2]
[1] Ìyẹn, àwọn tó ṣàì lọ sógun, àmọ́ tí wọn kò mú àwáwí irọ́ wá. [2] Àṣẹ náà dé nínú āyah 118 níwájú.
アラビア語 クルアーン注釈:
 
対訳 節: (106) 章: 悔悟章
章名の目次 ページ番号
 
クルアーンの対訳 - ヨルバ語対訳 - Abu Rahima Mikhail - 対訳の目次

アブ・ラヒーマ・ミカエル・アイクウェイニーによる翻訳

閉じる