ಪವಿತ್ರ ಕುರ್‌ಆನ್ ಅರ್ಥಾನುವಾದ - ಯೊರೂಬ ಅನುವಾದ * - ಅನುವಾದಗಳ ವಿಷಯಸೂಚಿ

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

ಅರ್ಥಗಳ ಅನುವಾದ ಶ್ಲೋಕ: (101) ಅಧ್ಯಾಯ: ಸೂರ ಅಲ್ -ಮಾಇದ
يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ لَا تَسۡـَٔلُواْ عَنۡ أَشۡيَآءَ إِن تُبۡدَ لَكُمۡ تَسُؤۡكُمۡ وَإِن تَسۡـَٔلُواْ عَنۡهَا حِينَ يُنَزَّلُ ٱلۡقُرۡءَانُ تُبۡدَ لَكُمۡ عَفَا ٱللَّهُ عَنۡهَاۗ وَٱللَّهُ غَفُورٌ حَلِيمٞ
Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, ẹ má ṣe máa bèèrè nípa àwọn n̄ǹkan sá. Tí A bá fi hàn yín, ó máa kó ìpalára ba yín. Tí ẹ bá sì bèèrè nípa (àwọn n̄ǹkan tó yẹ láti bèèrè nípa ẹ̀sìn) nígbà tí À ń sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ lọ́wọ́, A máa fi hàn yín. Allāhu ti ṣe àmójúkúrò nípa rẹ̀. Allāhu ni Aláforíjìn, Aláfaradà.¹
1. Ìyẹn ni pé, ìbéèrè tí ẹ bi Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - léèrè tí ó lè yọrí sí kí Allāhu - subhānahu wa ta'ālā - ṣe ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ n̄ǹkan ní ọ̀ran-anyàn fún yín, ohun tí kì í ṣe ọ̀ran-anyàn tẹ́lẹ̀ nínú ẹ̀sìn, Allāhu ti ṣe àmójúkúrò nípa rẹ̀ fún yín. Kò sì níí tipasẹ̀ ìbéèrè yín ṣe àwọn n̄ǹkan náà ní ọ̀ran-anyàn nítorí kí ẹ má baà kó ara yín sínú ìpalára.
ಅರಬ್ಬಿ ವ್ಯಾಖ್ಯಾನಗಳು:
 
ಅರ್ಥಗಳ ಅನುವಾದ ಶ್ಲೋಕ: (101) ಅಧ್ಯಾಯ: ಸೂರ ಅಲ್ -ಮಾಇದ
ಅಧ್ಯಾಯಗಳ ವಿಷಯಸೂಚಿ ಪುಟ ಸಂಖ್ಯೆ
 
ಪವಿತ್ರ ಕುರ್‌ಆನ್ ಅರ್ಥಾನುವಾದ - ಯೊರೂಬ ಅನುವಾದ - ಅನುವಾದಗಳ ವಿಷಯಸೂಚಿ

ಪವಿತ್ರ ಕುರ್‌ಆನ್ ಯೊರೂಬ ಅರ್ಥಾನುವಾದ - ಶೈಖ್ ಅಬೂ ರಹೀಮ ಮೀಕಾಯೀಲ್ ಐಕ್ವೀನಿ. ಮುದ್ರಣ: 1432 ಹಿ.

ಮುಚ್ಚಿ