पवित्र कुरअानको अर्थको अनुवाद - योरुबा अनुवाद * - अनुवादहरूको सूची

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

अर्थको अनुवाद श्लोक: (39) सूरः: सूरतु अाले इम्रान
فَنَادَتۡهُ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ وَهُوَ قَآئِمٞ يُصَلِّي فِي ٱلۡمِحۡرَابِ أَنَّ ٱللَّهَ يُبَشِّرُكَ بِيَحۡيَىٰ مُصَدِّقَۢا بِكَلِمَةٖ مِّنَ ٱللَّهِ وَسَيِّدٗا وَحَصُورٗا وَنَبِيّٗا مِّنَ ٱلصَّٰلِحِينَ
Nítorí náà, àwọn mọlāika pè é nígbà tí ó ń kírun lọ́wọ́ nínú ilé ìjọ́sìn, (wọ́n sọ pé): “Dájúdájú Allāhu ń fún ọ ní ìró ìdùnnú nípa (bíbí) Yahyā. Ó máa fi òdodo rinlẹ̀ nípa ọ̀rọ̀ kan láti ọ̀dọ̀ Allāhu.¹ (Ó máa jẹ́) aṣíwájú, tí kò kúndùn obìnrin.² (Ó máa jẹ́) Ànábì. Ó sì wà nínú àwọn ẹni rere.”
1. “Ọ̀rọ̀ kan láti ọ̀dọ̀ Allāhu”, òhun ni Ànábì ‘Īsā ọmọ Mọryam - kí ọlà Allāhu máa bá a - nítorí pé, Allāhu dá òun nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ àṣẹ Rẹ̀ “Jẹ́ bẹ́ẹ̀, ó sì máa jẹ́ bẹ́ẹ̀” gẹ́gẹ́ bí Allāhu - subhānahu wa ta‘ālā - ṣe fi rinlẹ̀ nínú sūrah yìí kan náà, āyah 59. Ẹ tún wo sūrah an-Nisā’; 4:171.
2. tàbí ẹni tí kò ju ẹ̀mí ara rẹ̀ sílẹ̀ fún ìfẹ́-inú àti yòdòyìndìn ayé.
अरबी व्याख्याहरू:
 
अर्थको अनुवाद श्लोक: (39) सूरः: सूरतु अाले इम्रान
अध्यायहरूको (सूरःहरूको) सूची رقم الصفحة
 
पवित्र कुरअानको अर्थको अनुवाद - योरुबा अनुवाद - अनुवादहरूको सूची

पवित्र कुर्आनको अर्थको योरुबा भाषामा अनुवाद, अनुवादक शैख अबू रहीमा मिकाईल एकविनी, प्रकाशन : १४३२ हिज्री ।

बन्द गर्नुस्