Қуръони Карим маъноларининг таржимаси - Йўрубача таржима * - Таржималар мундарижаси

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Маънолар таржимаси Оят: (39) Сура: Сод сураси
هَٰذَا عَطَآؤُنَا فَٱمۡنُنۡ أَوۡ أَمۡسِكۡ بِغَيۡرِ حِسَابٖ
Èyí ni ọrẹ Wa. Nítorí náà, fi tọrẹ tàbí kí ó mú un dání¹ láì níí ní ìṣírò.²
1. Gbólóhùn yìí “Èyí ni ọrẹ Wa.” Ó túmọ̀ sí “èyí ni àwọn dúkìá ayé tí A fi ta ọ́ ní ọrẹ”. Ìtúmọ̀ yìí sì ni mo lò. Àmọ́ “Èyí ni ọrẹ Wa.” tún túmọ̀ sí “èyí ni àwọn àlùjànnú tí A fi ta ọ́ ní ọrẹ.” Pẹ̀lú ìtúmọ̀ kejì yìí. Ohun tí ó máa jẹ́ ìtúmọ̀ fún gbólóhùn ìparí āyah náà máa lọ báyìí pé, “Tu àwọn àlùjànnú tí o bá fẹ́ tú kúrò lórí ìgbèkùn sílẹ̀ tàbí kí o de èyí tí ó bá fẹ́ mọ́lẹ̀ sórí ìgbèkùn, kò sì níí sí ìbéèrè fún ọ lórí rẹ̀ ní Ọjọ́ Ìṣírò iṣẹ́.
2. Ìyẹn ni pé, Ànábì Sulaemọ̄n - kí ọlà Allāhu máa bá a - kò níí ṣe ìṣírò ní Ọjọ́ Ìṣírò-iṣẹ́ lórí èyí tí ó ná síta àti èyí tí ó ná fún ìgbádùn ara rẹ̀ nílé ayé.
Арабча тафсирлар:
 
Маънолар таржимаси Оят: (39) Сура: Сод сураси
Суралар мундарижаси Бет рақами
 
Қуръони Карим маъноларининг таржимаси - Йўрубача таржима - Таржималар мундарижаси

Қуръон Карим маъноларининг йўрубача таржимаси. Мутаржим: шайх Абу Раҳима Микоил Айквайний, 1432 ҳ. йили нашрдан чиққан.

Ёпиш