《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 * - 译解目录

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

含义的翻译 段: (226) 章: 拜格勒
لِّلَّذِينَ يُؤۡلُونَ مِن نِّسَآئِهِمۡ تَرَبُّصُ أَرۡبَعَةِ أَشۡهُرٖۖ فَإِن فَآءُو فَإِنَّ ٱللَّهَ غَفُورٞ رَّحِيمٞ
Ìkóraró fún oṣù mẹ́rin wà fún àwọn tó búra pé àwọn kò níí súnmọ́ obìnrin wọn. Tí wọ́n bá ṣẹ́rí padà (láààrin ìgbà náà), dájúdájú Allāhu ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run.¹
1. Tí ọkùnrin bá sọ pé “Mo fi Allāhu búra, èmi kò níí súnmọ́ ìyàwó mi.” Òǹkà ọjọ́ tí kò fi níí súnmọ́ ìyàwó rẹ̀ lẹ́yìn ìbúra náà kò gbọdọ̀ tayọ oṣù mẹ́rin. Tí oṣù mẹ́rin bá bá a lórí ìpinnu rẹ̀ yìí, wọn yóò pa á láṣẹ pé kí ó padà síbi sísúnmọ́ ìyàwó rẹ̀ tàbí kí ó kọ̀ ọ́ sílẹ̀, ìyẹn nígbà tí ó bá kọ̀ jálẹ̀ láti padà síbi sísúnmọ́ ìyàwó rẹ̀ lẹ́yìn oṣù mẹ́rin.
阿拉伯语经注:
 
含义的翻译 段: (226) 章: 拜格勒
章节目录 页码
 
《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 - 译解目录

古兰经泰卢固语译解,艾布·拉赫曼·米卡伊里·艾库比尼长老翻译,伊历1432年出版发行。

关闭