《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 * - 译解目录

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

含义的翻译 段: (53) 章: 拜格勒
وَإِذۡ ءَاتَيۡنَا مُوسَى ٱلۡكِتَٰبَ وَٱلۡفُرۡقَانَ لَعَلَّكُمۡ تَهۡتَدُونَ
(Ẹ rántí) nígbà tí A fún (Ànábì) Mūsā ní Tírà àti ọ̀rọ̀-ìpínyà nítorí kí ẹ lè mọ̀nà.¹
1. Kíyè sí i, al-Furƙọ̄n “ọ̀rọ̀-ìpínyà” (ọ̀rọ̀ tó ń ṣe ìpínyà láààrin òdodo àti irọ́) jẹ́ ìròyìn àti àbùdá kan tí ń bẹ lára gbogbo tírà tí Allāhu - subhānahu wa ta‘ālā - fún gbogbo àwọn Ànábì Rẹ̀ - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá wọn -. Kì í ṣe pé ọ̀tọ̀ ni Tírà, ọ̀tọ̀ ni Furƙọ̄n. Ọmọ ‘Abbās - kí Allāhu yọ́nú sí àwọn méjèèjì - sọ pé, “Furƙọ̄n ni orúkọ fún àpapọ̀ gbogbo tírà Zabūr, Taorāt, ’Injīl àti Ƙur’ān. (Tọbariy) Ìdí sì nìyí tí al-Furƙọ̄n fi jẹ́ orúkọ mìíràn fún al-Ƙur’ān.
阿拉伯语经注:
 
含义的翻译 段: (53) 章: 拜格勒
章节目录 页码
 
《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 - 译解目录

古兰经泰卢固语译解,艾布·拉赫曼·米卡伊里·艾库比尼长老翻译,伊历1432年出版发行。

关闭