Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo - Firo yurbawiiwo * - Tippudi firooji ɗii

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

Firo maanaaji Aaya: (27) Simoore: Simoore koreeji imraan
تُولِجُ ٱلَّيۡلَ فِي ٱلنَّهَارِ وَتُولِجُ ٱلنَّهَارَ فِي ٱلَّيۡلِۖ وَتُخۡرِجُ ٱلۡحَيَّ مِنَ ٱلۡمَيِّتِ وَتُخۡرِجُ ٱلۡمَيِّتَ مِنَ ٱلۡحَيِّۖ وَتَرۡزُقُ مَن تَشَآءُ بِغَيۡرِ حِسَابٖ
Ò ń mú òru wọnú ọ̀sán.¹ Ò ń mú ọ̀sán wọnú òru.² Ò ń mú alààyè jáde lára òkú. Ò ń mú òkú jáde lára alààyè. O sì ń pèsè ìjẹ-ìmu àti ìgbádùn fún ẹni tí Ó bá fẹ́ láì níí ní ìṣírò.”³
1. Àsìkò ọ̀sán máa gùn, àsìkò òru sì máa kúrú.
2. Àsìkò ọ̀ru máa gùn, àsìkò ọ̀sán sì máa kúrú.
3. Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-Baƙọrah; 2:212.
Faccirooji aarabeeji:
 
Firo maanaaji Aaya: (27) Simoore: Simoore koreeji imraan
Tippudi cimooje Tonngoode hello ngoo
 
Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo - Firo yurbawiiwo - Tippudi firooji ɗii

Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo e ɗemngal yurba, firi ɗum ko mawɗo Abuu Rahiima Miikaa'iil aykuuniy. Muulngo hitaande 1432fergo

Uddude