《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 * - 译解目录

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

含义的翻译 段: (150) 章: 阿里欧姆拉尼
بَلِ ٱللَّهُ مَوۡلَىٰكُمۡۖ وَهُوَ خَيۡرُ ٱلنَّٰصِرِينَ
Allāhu sì ni Alárànṣe yín.¹ Ó sì lóore jùlọ nínú àwọn alárànṣe.²
1. Ohun tí “bal” (bí kò ṣe pé) ìbẹ̀rẹ̀ āyah yìí kó sínú ni pé, “ẹ má tẹ̀lé àwọn aláìgbàgbọ́ lẹ́yìn ìgbàgbọ́ òdodo yín nítorí pé, wọn kò lè ṣe àrànṣe fún yín bí kò ṣe Allāhu, Òun ni Alárànṣe yín”.
2. Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah as-Sọffāt; 37:125.
阿拉伯语经注:
 
含义的翻译 段: (150) 章: 阿里欧姆拉尼
章节目录 页码
 
《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译。 - 译解目录

古兰经泰卢固语译解,艾布·拉赫曼·米卡伊里·艾库比尼长老翻译,伊历1432年出版发行。

关闭