ترجمهٔ معانی قرآن کریم - ترجمه ى یوروبایی * - لیست ترجمه ها

PDF XML CSV Excel API
Please review the Terms and Policies

ترجمهٔ معانی آیه: (46) سوره: سوره آل عمران
وَيُكَلِّمُ ٱلنَّاسَ فِي ٱلۡمَهۡدِ وَكَهۡلٗا وَمِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ
Ó máa bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló àti nígbà tó bá dàgbà.¹ Ó sì wà nínú àwọn ẹni rere.”
1. Láti ọ̀dọ̀ bàbá Huraerah - kí Allāhu yọ́nú sí i -, láti ọ̀dọ̀ Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -, ó sọ pé, “Kò sí ẹni tí ó sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló àfi ọmọdé mẹ́ta; Ànábì ‘Īsā ọmọ Mọryam - kí ọlà Allāhu máa bá a -, ọmọdé kan ní àsìkò Juraej àti ọmọdé kan mìíràn.” Bukọ̄riy, Muslim àti ’Ahmad, èyí ni ẹ̀gbàwá ’Ahmad.
تفسیرهای عربی:
 
ترجمهٔ معانی آیه: (46) سوره: سوره آل عمران
فهرست سوره ها شماره صفحه
 
ترجمهٔ معانی قرآن کریم - ترجمه ى یوروبایی - لیست ترجمه ها

ترجمه ى معانی قرآن کریم به زبان یوروبایی. مترجم: شیخ ابو رحیمه میکائیل ایکوینی. سال چاپ: 1432هجرى قمرى.

بستن