Atọ́ka awọn ìtumọ̀ si èdè mìíràn

Ìtumọ̀ sí èdè Yorùbá - Abu Roheemah Mikail

Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Sheikh Abu Roheemah Mikail Ẹkọyẹni.

Ìtumọ̀ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì – ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah.

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Da'wah ti Rabwah àti Àjọ iṣẹ́-ìsìn fún àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní oríṣiríṣi èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Faranse - Rasheed Ma'aash

Rasheed Ma'aash ni ó túmọ̀ rẹ̀.

Ìtumọ̀ sí èdè Pọtuga - Helmi Nasr

Dr. Helmi Nasr ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.

Ìtumọ̀ sí èdè Romania - Islam4ro.com

Titumọ̀ awọn itumọ ti Kuraani Alapọn-ọnle si èdè Romania, o jade lati islam4ro.com

Ìtumọ̀ sí èdè Dutch - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ó jáde láti ọwọ́ Ibùdó ti n rí sí ọ̀rọ̀ Ìsìláàmù ti Netherlands. A ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.

Ìtumọ̀ sí èdè Tọ́kì - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ìsìláàmù Ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Azerbaijan - Ali Khan Mosaiv

Ali Khan Musayev ni o ṣe ìtumọ̀ rẹ. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.

Ìtumọ̀ sí èdè Macedonia - Ẹgbẹ́ àwọn onímọ̀ láti Makedóníà

Ẹgbẹ́ àwọn onímọ̀ láti Makedóníà ni wọ́n ṣe ìtumọ̀ àti àgbéyẹ̀wò rẹ̀.

Ìtumọ̀ sí èdè Bosnia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Serbia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Àjọ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah, àti Àjọ Iṣẹ́-ìránṣẹ́ fún Àkóónú Ẹ̀sìn Ísìláàmù ní Onírúurú Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Lithuania - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Da'wah ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́-sìn Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Ipepe ni Rabwah àti Àjọ Iṣẹ-isin Akoonu Ẹsin Islam ni awọn ede àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Tajik - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpèpè ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Kyrgyz - Shamsudeen Hakimov

Shamsuddin Hakimov Abdulkhaliq ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, a ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ.

Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Tagalog) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah ati Ẹgbẹ́ Iṣẹ Iranṣẹ fun Akoonu Ẹsin Islam ni Awọn Ede ati oju opo wẹẹbu IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Bisaya) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè Mìíràn, àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Maguindanao) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah àti Ẹgbẹ́ iṣẹ́ sísìn fún àkóónú ẹ̀sìn Islam ní àwọn èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ si èdè Ṣáínà – Muhammad Sulaiman

Muhammad Makin ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, Muhammad Suleiman àti àwọn ògbóǹkangí mìíràn nínú ẹ̀ka èdè ni wọ́n ṣe àgbéyẹ̀wò rẹ̀.

Ìtumọ̀ sí èdè Vietnamese - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpèpé ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ tó ń rí sí Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Oríṣiríṣi Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Khmer - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah àti Ẹgbẹ́ tó ń rí sí Àkóónú Ìsìláàmù ní oríṣiríṣi àwọn èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Farisí - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Àjọ Ìpèpé sí Ẹ̀sìn ní Rabwah àti Àjọ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Islam ní Oríṣiríṣi Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Telugu - Abdur-Rahiim ọmọ Muhammad

Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Abdur-Raheem ọmọ Muhammad.

Ìtumọ̀ sí èdè Gujarati - Rabila Al-Omary

Rabila Al-Umari ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.

Ìtumọ̀ sí èdè Kannada - Hamza Puttur

Muhammad Hamzah Batur ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ.

Ìtumọ̀ sí èdè Assamese - Rafiqul Islam Habibur Rahman

Ẹni tí ó túmọ̀ rẹ̀ ni Rafiikul Islam Habeebur-Rahmaan.

Ìtumọ̀ sí èdè Tamil - Umar Sherif - Ẹ̀dà ṣókí

Sheikh Umar Sherif bin Abdulsalam ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.

Ìtumọ̀ sí èdè Sinhalese - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Ìpènísìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Ìpèsè Àkóónú Ìsìláàmù ní Àwọn Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Swahili - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ó jáde láti ọwọ́ ìjọ tí ń fi oríṣiríṣi èdè ṣiṣẹ́ lórí àkòónú Islam.

Ìtumọ̀ sí èdè Amharic - Akadẹmi Africa

Ìtumọ̀ rẹ̀ wá láti ọwọ́ Muhammad Zain Zaharuddin. Ó jáde láti ọ̀dọ̀ Akadẹ́mì Áfíríkà.

Ìtumọ̀ sí èdè Kinyarwanda - Ẹgbẹ àwọn Musulumi ti Rwanda

O wá lati ọwọ́ Ẹgbẹ àwọn Musulumi ti Rwanda.

Ìtumọ̀ sí èdè Kirundi - Yusuf Gahiti

Yusuf Gheiti ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. Ó jáde láti ọwọ́ Àjọ ti ilẹ̀ Áfíríkà fún idagbasoke.

Ìtumọ̀ sí èdè Moori - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ

Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sí-ẹ̀sìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́ Ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Àwọn Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.

Ìtumọ̀ sí èdè Akan - Ashanti - Harun Ismail

Sheikh Haarun Ismail ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.
:
0:00 0:00