Agbedegbẹyọ Kuraani Alapọn-ọnle
Láti pèsè àwọn àlàyé ìtumọ̀ ati ìtumọ̀ si èdè mìíràn tí o fi ọkàn balẹ̀ fún àwọn ìtumọ̀ Kuraani Alapọn-ọnle pẹ̀lú àwọn èdè ayé
Ìtumọ̀ sí èdè Yorùbá - Abu Roheemah Mikail
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Sheikh Abu Roheemah Mikail Ẹkọyẹni.Àlàyé ìtumọ̀ Kuraani tí ó rọrùn
Àlàyé ìtumọ̀ Kuraani tí ó rọrùnÈdè Lárúbáwá - Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Kur'aanil Kariim ní èdè Lárúbáwá, ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Èdè Lárúbáwá - At-Tafsiirul Muyassar
Ti ó jáde láti ilé-iṣẹ́ Ọba Fahad fún títẹ Kuraani ni ìlú Madina.Èdè Lárúbáwá - Ìtumọ̀ àwọn gbólóhùn
Láti inú tira As-Siraaj Fii Bayaani Gariibil Qur'an.An-Nafahaat Al-Makkiyyah - Muhammad ọmọ Salih Ash-shawiy
An-Nafahaatul Makkiyyah fii Tafsiir Kitaab Rabbil Bariyyah ti Sheekh Muhammad bin Soolih Ash-Shaawii.تفسير السعدي - عبد الرحمن بن ناصر السعدي
تيسير الكريم الرحمن في تفسير كلام المنان.Ìtumọ̀ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì – ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah.
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Da'wah ti Rabwah àti Àjọ iṣẹ́-ìsìn fún àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní oríṣiríṣi èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì - Ilé-iṣẹ́ Noor International
O wá lati Markazu Nuur International.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì - Taqiyyu Deen Al-Hilaaliy ati Muhsin Khan
Àwọn tí wọ́n ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Taqiyyu Deen Hilaaliy ati Muhammad Muhsin Khan.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì - Dr. Waleed Al-Umary - iṣẹ n lọ lọ́wọ́ lórí ẹ.
Dr. Walid Bleyhesh Al-Umari ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Faranse - Rasheed Ma'aash
Rasheed Ma'aash ni ó túmọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Faranse - Ilé-iṣẹ́ Noor International
Dr. Nabil Ridwan ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, tí ó jáde láti Ilé-iṣẹ́ Noor International.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Faranse - Muhammad Hamiidullah
Muhammad Hamidullah ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Faranse fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Sípéènì - Isa Garcia
Muhammad Isa Garcia ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Sípéènì - Ilé-iṣẹ́ Noor International
O wa lati Markazu Nuur International.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ si ede Sípéènì (ede latin Amẹ́ríkà) – ile-iṣẹ Noor International
Ẹ̀dà èdè Látìn Amẹ́ríkà, ti a gbé jáde láti ọwọ́ Ilé-iṣẹ́ Noor International.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Sípéènì fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Pọtuga - Helmi Nasr
Dr. Helmi Nasr ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Gíríìkì - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ̀ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Da'wah ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Oríṣiríṣi Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Jámánì - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpèpè ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Ìsìláàmù ní Àwọn Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Jámánì - Frank Bubenheim
Tí a túmọ̀ láti ọwọ́ Abdullah Al-Samet (Frank Bubenheim) ati Dr. Nadeem Ilyas.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Jámánì - Abuu Ridọ
Ali Abu Ridha Muhammad ọmọ Ahmad ọmọ Rasul ni o túmọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Italy - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Da'awah ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Islam ní Àwọn Èdè Oríṣiríṣi àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Itálíà fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Bulgaria
Titumọ̀ awọn itumọ ti Kuraani si èdè BùlgáríàÌtumọ̀ sí èdè Romania - Islam4ro.com
Titumọ̀ awọn itumọ ti Kuraani Alapọn-ọnle si èdè Romania, o jade lati islam4ro.comÌtumọ̀ sí èdè Dutch - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ó jáde láti ọwọ́ Ibùdó ti n rí sí ọ̀rọ̀ Ìsìláàmù ti Netherlands. A ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Sweden - Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpèpè ní Rabwah ati Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsin fún Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Tọ́kì - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ìsìláàmù Ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Tọ́kì - Sha'baan Britsh
Sha'baan Britsh ni o tumọ rẹ. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Tọ́kì - Dr. Ali Ozek àti àwọn mìíràn
Ali Ozek àti àwọn mìíràn pẹ̀lú rẹ̀ ni wọ́n ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, a ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Tọ́kì fun Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.الترجمة التركية - تفسير السعدي
ترجمة تفسير السعدي إلى اللغة التركية.Ìtumọ̀ sí èdè Azerbaijan - Ali Khan Mosaiv
Ali Khan Musayev ni o ṣe ìtumọ̀ rẹ. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Azerbaijan fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Georgia
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpèsìnsìn ni Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ni Onírúurú Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Macedonia - Ẹgbẹ́ àwọn onímọ̀ láti Makedóníà
Ẹgbẹ́ àwọn onímọ̀ láti Makedóníà ni wọ́n ṣe ìtumọ̀ àti àgbéyẹ̀wò rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Albania - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Ìpèpe sínú Ẹ̀sìn ní Rabwah àti Àjọ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní onírúurú èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Albania - Hassaan Naahi
Hassaan Naahi ni ó túmọ̀ rẹ̀, tí o jáde láti Ile-ẹkọ Albania fun ero Islam ati ọlaju Islam.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Bosnia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Bosnia- Muhammad Mihanovich
Muhammad Mehanovich ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Bosnia- Besim Korkut
Besim Korkut ni o ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Bosnia fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Russia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipe-si-ẹsin ni Rabwah àti Ẹgbẹ́ Ìṣe-ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Awọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Russia - Abuu Aadil
Abuu Aadil ni ó túmọ̀ rẹ̀.الترجمة الروسية - تفسير السعدي
ترجمة تفسير السعدي إلى اللغة الروسية.Ìtumọ̀ sí èdè Belarus - Krivtsov
Ìtumọ̀ ti Alexia Ismail Krivtsov.Ìtumọ̀ sí èdè Serbia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Àjọ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah, àti Àjọ Iṣẹ́-ìránṣẹ́ fún Àkóónú Ẹ̀sìn Ísìláàmù ní Onírúurú Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Serbia fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Croatia - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ tó ń rí sí Àkóónú ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àti ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Lithuania - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Da'wah ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́-sìn Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Ukraine - Mikhailo Yaqubovic
Dr. Mikhailo Yakubovich ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Kazakh - Khalifa Altay
Khalifa Altay ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Ipepe ni Rabwah àti Àjọ Iṣẹ-isin Akoonu Ẹsin Islam ni awọn ede àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek - Muhammad Saadiq
Muhammad Sadiq Muhammad Yusuf ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek - Alauddin Mansour
Alauddin Mansour ni o ṣe ìtumọ̀ rẹ. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Uzbek fún At-Tafsiirul Muyassar
Titumọ̀ Tafsir Al-Muyassar si èdè Uzbek, tí Ismail Yaqub ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ láti Ilé-iṣẹ́ Ẹ̀sìn Islam IxlosOrg sì ṣe àtúnyẹ̀wò rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Tajik - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpèpè ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ fún Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Tajik - Khawja Mirov Khawja Miir
Khawja Mirov Khawja Miir ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Kyrgyz - Shamsudeen Hakimov
Shamsuddin Hakimov Abdulkhaliq ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, a ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Kyrgyz fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Circassian - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọ́n túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Ìpènísìn ní Rabwah àti Àjọ tó ń rí sí àkóónú Ìsìláàmù ní oríṣiríṣi èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Indoneṣia - Ilé-iṣẹ́ Sabeq
Ó jáde láti ọwọ́ Ilé-iṣẹ́ Sabeq. A ti ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Indoneṣia - Ilé-iṣẹ́ ìjọba ti n ri si ọrọ ẹsin
Eyi ti o jade lati ọdọ Ilé-iṣẹ́ ìjọba ti o n ri si ọrọ ẹsin ni Indonesia. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn ìròrí, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Indoneṣia - Ilé-iṣẹ́ Ọba Fahd fún títẹ Kuraani ni ilu Madina
Eyi ti o jade lati ọwọ Ilé-iṣẹ́ ìjọba ti n ri si ọrọ ẹsin ni Indonesia. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Indoneṣia fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.الترجمة الإندونيسية - تفسير السعدي
ترجمة تفسير السعدي إلى اللغة الإندونيسية.Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Tagalog) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah ati Ẹgbẹ́ Iṣẹ Iranṣẹ fun Akoonu Ẹsin Islam ni Awọn Ede ati oju opo wẹẹbu IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Tagalog) fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Bisaya) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Àwọn Èdè Mìíràn, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Maranao)
Ìtumọ̀ rẹ̀ wá láti ọwọ́ Sheikh Abdul Aziz Guru Alim Saro Mentang.Ìtumọ̀ sí èdè Filipino (Maguindanao) - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah àti Ẹgbẹ́ iṣẹ́ sísìn fún àkóónú ẹ̀sìn Islam ní àwọn èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Maleṣia - Abdullaah Baasimiyya
Abdullah Muhammad Basimiyah ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ si èdè Ṣáínà – Muhammad Sulaiman
Muhammad Makin ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀, Muhammad Suleiman àti àwọn ògbóǹkangí mìíràn nínú ẹ̀ka èdè ni wọ́n ṣe àgbéyẹ̀wò rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Ṣáínà - Muhammad Makin
Muhammad Makin ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ si èdè Ṣáínà – BASAA’IR
Ma Yulong ni o túmọ̀ rẹ, tí ó jáde láti ọ̀dọ̀ WAQFU BASAA’IR LI KHID’MATIL QUR’ANIL KAREEM WA ULUUMIH.Ìtumọ̀ sí èdè Ṣáínà fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Uyghur - Muhammad Solih
Ṣeik Muhammad Salih ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Uyghur fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Japan - Saheed Sato
Saeed Satu ni o ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Japan fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Itumọ si èdè Korea- Hamid Choi
Hamid Tṣuwi ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Korean - Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sínú-ẹ̀sìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Oríṣiríṣi Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Vietnamese - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ìpèpé ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ tó ń rí sí Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Oríṣiríṣi Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Vietnamese - Hasan Abdul Karim
Hasan Abdul Karim ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Vietnamese fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Thailand - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpèsínú-ẹ̀sìn ní Rabwah àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní Oríṣiríṣi Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Thailand - Ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀
Ó jáde láti ọwọ́ Ẹgbẹ́ àwọn tó jáde ní Yunifásítì àti àwọn ilé ẹ̀kọ́ ní Thailand. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Ìtumọ̀ sí èdè Thai fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Khmer - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ikọ̀ Ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹlu Ẹgbẹ́ Ipepe ni Rabwah àti Ẹgbẹ́ tó ń rí sí Àkóónú Ìsìláàmù ní oríṣiríṣi àwọn èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Khmer - Ẹgbẹ́ Ìdàgbàsókè Àwùjọ Ìsìlààmù
O wa lati ọwọ́ Ẹgbẹ́ to n ri si ìdàgbàsókè àwùjọ Islām ni ìlú Cambodia.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Khmer fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Farisí - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Àjọ Ìpèpé sí Ẹ̀sìn ní Rabwah àti Àjọ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Islam ní Oríṣiríṣi Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Farisí - Tafsir As-Sa'di
Titumọ tafsir As-Sa'di si èdè FarisíÌtumọ̀ sí èdè Farisí fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Farisí - Tafsir As-Sa'di
Titumọ tafsir As-Sa'di si èdè FarisíÌtumọ̀ sí èdè Dari - Muhammad Anwar Badakhshani
Molvi Muhammad Anwar Badakhshani ni ó túmọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Kurdistan - Muhammad Salih Bamuki
Muhammad Salih Bamoki ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Kurdistan - Solahudeen
Ẹni tí ó túmọ̀ rẹ̀ ni Solahudeen Abdulkarim.Ìtumọ̀ sí èdè Kurd fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Kurmanji ti Kurdistan - Ismail Sagheri
Dr. Ismail Sagheri ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Pashto - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpènísínsìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́-ìránṣẹ́ fún Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Àwọn Èdè, pẹ̀lú ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Pashto - Abuu Zakariyya
Abu Zakariyyaa Abdus-Salaam ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Pashto - Sarfaraz
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Molavi Janbaz SarfarazÌtumọ̀ sí èdè Pashto fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Hébérù - Ẹgbẹ́ Dar As-Salam
O wa lati Ilé-iṣẹ́ Darus Salaam ní Jerúsálẹ́mù.Ìtumọ̀ sí èdè Urdu - Muhammad Junagarhi
Muhammad Ibrahim Junagarhi ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
الترجمة الأردية - تفسير السعدي
ترجمة تفسير السعدي إلى اللغة الأردية.Ìtumọ̀ sí èdè India - Azeezul Haqq Al-Umari
Azeezul Haqq Al-Umari ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Hindi fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Bangali - Abubakar Zakariyya
Èdè Bangali tí Dr. Abubakar Muhammad Zakariyya ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Bangali fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Marathi - Muhammad Shafi'i Ansari
Muhammad Shafi Ansari ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Telugu - Abdur-Rahiim ọmọ Muhammad
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Abdur-Raheem ọmọ Muhammad.Ìtumọ̀ sí èdè Telugu fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Gujarati - Rabila Al-Omary
Rabila Al-Umari ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Malayalam - Abdul Hameed Haidar ati Kan'hi Muhammad
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Abdul Hameed Haidar Al-Madani ati Kunahi Muhammad.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Malayalam fun Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Malayalam fun Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Kannada - Hamza Puttur
Muhammad Hamzah Batur ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó ile-iṣẹ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Kannada - Basheer Mysori
A ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ láti ọwọ́ Ṣẹ́ìk Bashir Maisuri. A ṣe agbekalẹ rẹ lábẹ́ àbójútó Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ.Ìtumọ̀ sí èdè Assamese - Rafiqul Islam Habibur Rahman
Ẹni tí ó túmọ̀ rẹ̀ ni Rafiikul Islam Habeebur-Rahmaan.Ìtumọ̀ sí èdè Assamese fun Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Punjabi - Aarif Halim
Aarif Haleem ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Tamil - Umar Sherif - Ẹ̀dà ṣókí
Sheikh Umar Sherif bin Abdulsalam ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Tamil - Umar Sherif
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Sheikh Umar Sherif bin Abdussalam.Ìtumọ̀ sí èdè Tamil - Abdul Hameed Baqoi
Sheikh Abdul Hameed Baqoi ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Tamil fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Sinhalese - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Ìpènísìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Ìpèsè Àkóónú Ìsìláàmù ní Àwọn Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Sinhalese fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Nepal - Ẹgbẹ́ Ahlul Hadiith
Ti a gbé jáde láti ọwọ́ Ẹgbẹ́ àwọn ahlul hadith ti àárín gbùngbùn ní ìlú Nepal.Ìtumọ̀ sí èdè Swahili - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ó jáde láti ọwọ́ ìjọ tí ń fi oríṣiríṣi èdè ṣiṣẹ́ lórí àkòónú Islam.Ìtumọ̀ sí èdè Swahili - Ali Muhsin Al-Barwaany
Ali Muhsin Al-Barwaany ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Swahili - Abdullaah Muhammad ati Naasir Khamiis
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Dr. Abdullaah Muhammad Abu Bakr ati Sheikh Naasir Khamiis.الترجمة السواحيلية - تفسير السعدي
ترجمة تفسير السعدي إلى اللغة السواحيلية.Ìtumọ̀ sí èdè Somalia - Abdullaah Hasan Yaqub
Abdullah Hasan Yakub ni ó túmọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Amharic - Akadẹmi Africa
Ìtumọ̀ rẹ̀ wá láti ọwọ́ Muhammad Zain Zaharuddin. Ó jáde láti ọ̀dọ̀ Akadẹ́mì Áfíríkà.Ìtumọ̀ sí èdè Amharic - Muhammad Saadiq
Sheik Muhammad Sadiq àti Muhammad Sani Habib ni wọ́n ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Hausa - Abu Bakr Goomi
Abu Bakr Mahmud Gumi ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. A ṣe agbekalẹ rẹ labẹ abojuto ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ, ati pe itumọ ti ipilẹ wa fun ṣíṣe àfihàn èrò, ati igbelewọn, ati ìdàgbàsókè ti n tẹ síwájú.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Oromo - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Àjọ Ìpèpé ní Rabwah àti Àjọ tó ń rí sí iṣẹ́ àkóónú Ẹ̀sìn Ìsìlámù ní àwọn èdè oríṣiríṣi àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Oromo - Ghali Ababor
itumọ wá lati ọwọ Gali Ababor Abaguna.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Malagasy - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Àjọ Ìpèpè ní Rabwah, àti Àjọ Iṣẹ́-ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Islam ní oríṣiríṣi Èdè àti ojú-òpó IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Luhya - Ìjọ Àgbáyé fún Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ àti Àṣà
O jade lati ọwọ́ Ìjọ Àgbáyé fún Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ àti Àṣà.Ìtumọ̀ sí èdè Afar - Mahmud Abdulkadir Hamza
Ìtumọ̀ rẹ̀ wá láti ọwọ́ ẹgbẹ́ àwọn onímọ̀ tí Sheikh Mahmoud Abdul Qadir Hamza ń darí wọn.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Luganda- Ẹgbẹ́ ti Áfríkà fún ìdàgbàsókè
O wá lati ọwọ́ Àjọ ti ilẹ̀ Áfíríkà fún idagbasoke.Ìtumọ̀ sí èdè Inko - Sulaiman Kanti
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Fodié Souleymane Kanté.Ìtumọ̀ sí èdè Inko - Baba Mamadi
Ẹni tí ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀ ni Karamo. Baba Mamadi Jani.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Kinyarwanda - Ẹgbẹ àwọn Musulumi ti Rwanda
O wá lati ọwọ́ Ẹgbẹ àwọn Musulumi ti Rwanda.Ìtumọ̀ sí èdè Kirundi - Yusuf Gahiti
Yusuf Gheiti ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀. Ó jáde láti ọwọ́ Àjọ ti ilẹ̀ Áfíríkà fún idagbasoke.Ìtumọ̀ sí èdè Moori - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ifọwọsowọpọ Ẹgbẹ́ Ìpè-sí-ẹ̀sìn ní Rabwah, àti Ẹgbẹ́ Iṣẹ́ Ìsìn fún Àkóónú Ẹ̀sìn Ísílámù ní Àwọn Èdè, àti ìkànnì IslamHouse.com.Ìtumọ̀ sí èdè Dagbani - Muhammad Baba Ghotobo
Muhammad Baba Ghatoubou ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Chichewa - Khalid Ibrahim Bitiyala
Khaled Ibrahim Bitalla ni ó túmọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Akan - Ashanti - Harun Ismail
Sheikh Haarun Ismail ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Yau - Muhammad ọmọ Abdul-Hamiid Silika
Mohammed ọmọ Abdulhamid Slika ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Ìtumọ̀ sí èdè Fulani - Ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamọ
Ẹgbẹ́ láti ilé-iṣẹ́ Ruwwaadut Tarjamah ni wọn túmọ̀ rẹ ni ifọwọsowọpọ pẹ̀lú Àjọ Ipepe ni Rabwah àti Àjọ Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ fún Àkóónú Isilaamu ní Àwọn Èdè àti ìkànnì IslamHouse.com.Please review the Terms and Policies
Ìtumọ̀ sí èdè Fulani fún Al-Mukhtasar Fii Tefsiiril Qur'anil Kariim
Ti ilé-iṣẹ́ Tafsiri fún Ẹ̀kọ́ Kùránì ṣe jáde.Ìtumọ̀ sí èdè Lingala - Muhammad Balangogo
Zakaria Muhammad Balangogo ni ó ṣe ìtumọ̀ rẹ̀.Please review the Terms and Policies
الترجمة الشونا - معهد دار العلم
صادرة عن معهد دار العلم (إقرأ) بإشراف الشيخ عبد الله أديني.الترجمة الزولو - عادل جعفر
ترجمها الشيخ عادل جعفر مولتشو.Encyclopedia Objectives
We strive to provide translations and interpretations of the meanings of the Quran in various world languages, with continuous improvements.
A Reliable Online Reference
We provide reliable translations of the meanings of the Qur'an, based on the methodology of Ahlus-Sunnah wal-Jama'ah, as an alternative to untrustworthy online sources.
Multiple Electronic Formats
We provide translations in multiple electronic formats that keep up with the advancement of smart devices and meet the needs of website and application developers.
Free Access
We strive to disseminate the benefit of translations and make them available for free, facilitating access through search engines and global information sources.
Key Statistics
The encyclopedia's statistics reflect its broad impact and highlight the key aspects of benefiting from its content.
100+ Millions
API Calls
15+ Millions
Visits
4+ Millions
Downloads
100+
Translations
Iṣẹ àwọn oluṣẹda sọfitiwia ati apilikeṣan
Awọn iṣẹ ti a darí si awọn oluṣẹda sọfitiwia ni ero lati pese akoonu ti oluṣẹda nilo láti ṣẹ̀dá sọfitiwia rẹ ti o ni ibatan si Kuraani Alapọn-ọnle
API DocsXML
Gbigba ẹda awọn ìtumọ̀ si èdè mìíràn silẹ ni àwòrán faili Excel XML
CSV
Gbigba ẹda awọn ìtumọ̀ si èdè mìíràn silẹ ni àwòrán faili Excel CSV
Excel
Gbigba ẹda awọn ìtumọ̀ si èdè mìíràn silẹ ni àwòrán faili Excel Excel